Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Reward of Saints: Reigning for ever and ever
Àwọn ẹsẹ nípa Reigning for ever and ever
Òru kì yóò sí mọ́; wọn kò sì ní wa ìmọ́lẹ̀ fìtílà, tàbí ìmọ́lẹ̀ oòrùn; nítorí pé Olúwa Ọlọ́run ni yóò tan ìmọ́lẹ̀ fún wọn: wọn ó sì máa jẹ ọba láé àti láéláé.