Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Silver: Ornaments and hooks for the pillars of the tabernacle
Àwọn ẹsẹ nípa Ornaments and hooks for the pillars of the tabernacle
Gbogbo òpó ti ó wà ní àyíká àgbàlá náà ni a ó fi fàdákà ṣo pọ̀ àti ìkọ́, àti ihò ìtẹ̀bọ̀ idẹ.
pẹ̀lú òpó mẹ́rin àti ihò ìtẹ̀bọ̀ idẹ mẹ́rin. Ìkọ́ àti ìgbànú wọn jẹ́ fàdákà, a sì bo orí wọn pẹ̀lú fàdákà.