Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness: Know the secret of the Lord
Àwọn ẹsẹ nípa Know the secret of the Lord
Olúwa fi ọkàn tán, àwọn tí o bẹ̀rù u rẹ̀; ó sọ májẹ̀mú rẹ̀ di mí mọ̀ fún wọn.
Nítorí Olúwa kórìíra ènìyàn aláyídáyidà ṣùgbọ́n a máa fọkàn tán ẹni dídúró ṣinṣin.