Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness: Are delivered out of all troubles
Àwọn ẹsẹ nípa Are delivered out of all troubles
Ìpọ́njú àwọn olódodo pọ̀, ṣùgbọ́n Olúwa gbà wọ́n kúrò nínú gbogbo rẹ̀.
A gba olódodo kúrò lọ́wọ́ ibi dípò o rẹ̀, ibi wá sórí ènìyàn búburú.