Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pilgrims and Strangers: Have the example of Christ
Àwọn ẹsẹ nípa Have the example of Christ
Jesu sì wí fún un pé, “Àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ ní ihò, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run sì ní ìtẹ́; ṣùgbọ́n Ọmọ Ènìyàn kò ní ibi tí yóò fi orí rẹ̀ lé.”