Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Modern Samaria: Had no intercourse or dealings with the Jews
Àwọn ẹsẹ nípa Had no intercourse or dealings with the Jews
Ó sì rán àwọn ìránṣẹ́ lọ sí iwájú rẹ̀. Nígbà tí wọ́n sì lọ wọ́n wọ ìletò kan tí í ṣe ti ará Samaria láti pèsè sílẹ̀ dè é.
Wọn kò sì gbà á, nítorí pé ó ń lọ sí Jerusalẹmu.
Obìnrin ará Samaria náà sọ fún un pé, “Júù ni ìwọ, obìnrin ará Samaria ni èmi. Èétirí tí ìwọ ń béèrè ohun mímu lọ́wọ́ mi?” (Nítorí tí àwọn Júù kì í bá àwọn ará Samaria ṣe pọ̀.)