Fò sí àkóónú
Saamu 51:18-19

Àdúrà fún ìmúpadàbọ̀sípò Síónì

Saamu 51:18-19
18
Ṣe rere ní dídùn inú rẹ sí Sioni, ṣe rere; tún odi Jerusalẹmu mọ.
19
Nígbà náà ni inú rẹ yóò dùn sí ẹbọ òdodo, pẹ̀lú ọrẹ ẹbọ sísun àti ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ọrẹ ẹbọ sísun, nígbà náà ni wọn yóò fi akọ màlúù rú ẹbọ lórí pẹpẹ rẹ.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options