Fò sí àkóónú
Òwe 24:1-2

Má ṣe ṣe ìlara àwọn ènìyàn búburú

Òwe 24:1-2
1
Má ṣe ṣe ìlara àwọn ènìyàn búburú má ṣe jẹ́ kí àwùjọ wọn wù ọ́;
2
nítorí ọkàn wọn ń gbèrò ohun búburú, ètè wọn sì ń sọ̀rọ̀ nípa dídá rúgúdù sílẹ̀.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options