Fò sí àkóónú
1 Kronika 9:14-16

Àwọn ọmọ Léfì àti iṣẹ́ tẹ́ńpìlì

1 Kronika 9:14-16
14
Ní ti àwọn ará Lefi: Ṣemaiah ọmọ Haṣubu, ọmọ Asrikamu, ọmọ Haṣabiah ará Merari;
15
Bakibakari, Hereṣi, Galali àti Mattaniah, ọmọ Mika, ọmọ Sikri, ọmọ Asafu;
16
Obadiah ọmọ Ṣemaiah, ọmọ Galali, ọmọ Jedutuni; àti Berekiah ọmọ Asa, ọmọ Elkana, tí ó ń gbé nínú àwọn ìlú àwọn ará Netofa.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options