Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Zuph: 1. A Kohathite
Àwọn ẹsẹ nípa 1. A Kohathite
Ọkùnrin kan wà, láti Ramataimu-Sofimu, láti ìlú olókè Efraimu, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Elkana, ọmọ Jerohamu, ọmọ Elihu, ọmọ Tohu, ọmọ Sufu, ará Efrata.
ọmọ Sufu, ọmọ Elkana, ọmọ Mahati, ọmọ Amasai,