Zuph
A tún mọ̀ ọ́n sí: Zophai
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Zuph
Ọkùnrin kan wà, láti Ramataimu-Sofimu, láti ìlú olókè Efraimu, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Elkana, ọmọ Jerohamu, ọmọ Elihu, ọmọ Tohu, ọmọ Sufu, ará Efrata.
Elkana ọmọ rẹ̀, Sofai ọmọ rẹ̀ Nahati ọmọ rẹ̀,
ọmọ Sufu, ọmọ Elkana, ọmọ Mahati, ọmọ Amasai,