Nahath
A tún mọ̀ ọ́n sí: Tohu, Toah
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Nahath
Ọkùnrin kan wà, láti Ramataimu-Sofimu, láti ìlú olókè Efraimu, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Elkana, ọmọ Jerohamu, ọmọ Elihu, ọmọ Tohu, ọmọ Sufu, ará Efrata.
Elkana ọmọ rẹ̀, Sofai ọmọ rẹ̀ Nahati ọmọ rẹ̀,
ọmọ Elkana, ọmọ Jerohamu, ọmọ Elieli, ọmọ Toha,