Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Witness of the Holy Spirit: As exalted to be a Prince and Saviour to give repentance, &c

2 ẹsẹ · 17 abala

Àwọn ẹsẹ nípa As exalted to be a Prince and Saviour to give repentance, &c

  1. Òun ni Ọlọ́run fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ gbé gẹ́gẹ́ bí Ọmọ-aládé àti Olùgbàlà láti fi ìrònúpìwàdà àti ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ fún Israẹli.

  2. Àwa sì ni ẹlẹ́rìí nǹkan wọ̀nyí, àti gẹ́gẹ́ bí Ẹ̀mí Mímọ́ ti ṣe ẹlẹ́rìí pẹ̀lú, tí Ọlọ́run fi fún àwọn tí ó gbà á gbọ́.”