Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Walking with God: Not after the flesh, but after the Spirit

2 ẹsẹ · 17 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Not after the flesh, but after the Spirit

  1. Nítorí náà, kò sí ìdálẹ́bi nísinsin yìí fún àwọn tí ó wà nínú Kristi Jesu, àwọn tí kò rìn nípa ti ara, bí kò ṣe nípa ti Ẹ̀mí.

  2. Ǹjẹ́ mo ní, ẹ máa rìn nípa ti Ẹ̀mí, ẹ̀yin kì yóò sì mú ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara ṣẹ.