Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Vows: The hire of a prostitute or price of a dog could not be the subject of
Àwọn ẹsẹ nípa The hire of a prostitute or price of a dog could not be the subject of
Ìwọ kò gbọdọ̀ mú owó iṣẹ́ panṣágà obìnrin tàbí ọkùnrin wá sí ilé Olúwa Ọlọ́run rẹ láti fi san ẹ̀jẹ́ kankan; nítorí Olúwa Ọlọ́run rẹ kórìíra àwọn méjèèjì.