Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Virtue: Power 2 ẹsẹ · 2 abala Wá "Virtue" Gbogbo 4 Excellence 2 Power 2 Àwọn ẹsẹ nípa Power Luku 6:19Gbogbo ìjọ ènìyàn sì ń fẹ́ láti fọwọ́ kàn án, nítorí tí àṣẹ ń jáde lára rẹ̀, ó sì mú gbogbo wọn láradá.Luku 8:46Jesu sì wí pé, “Ẹnìkan fi ọwọ́ kàn mí: nítorí tí èmí mọ̀ pé, àṣẹ jáde lára mi.”