Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Uzziel: 1. A son of Kohath
Àwọn ẹsẹ nípa 1. A son of Kohath
Àwọn ọmọ Kohati ni: Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli. Kohati lo ẹ̀tàléláádóje (133) ọdún láyé.
Àwọn ọmọ Usieli ni: Miṣaeli, Elsafani àti Sitiri.
Mose pe Miṣaeli àti Elsafani ọmọ Usieli tí í ṣe arákùnrin Aaroni, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ wá, kí ẹ sì gbé àwọn arákùnrin yín jáde kúrò níwájú ibi mímọ́ lọ sí ẹ̀yìn ibùdó.”