Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ulai: A river of Chaldea.

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A river of Chaldea.

  1. Nínú ìran náà, mo rí ara mi nínú ilé ìṣọ́ ní Susa ní agbègbè ìjọba Elamu: nínú ìran náà mo wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò Ulai.

  2. Mo gbọ́ ohùn ènìyàn ní ẹ̀gbẹ́ Ulai, tí ó ń ké pé “Gabrieli, sọ ìtumọ̀ ìran náà fún ọkùnrin yìí.”