Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tychicus: Sent to Ephesus

3 ẹsẹ · 5 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Sent to Ephesus

  1. Tikiku, arákùnrin olùfẹ́ àti ìránṣẹ́ olóòtítọ́ nínú Olúwa yóò sọ ohun gbogbo dí mí mọ̀ fún yín, kí ẹ̀yin pẹ̀lú lè mọ̀ bí nǹkan ti rí fún mí àti bí mo tí ń ṣe sí.

  2. Ẹni tí mo rán sí yín nítorí èyí náà, kí ẹ lè mọ̀ bí a tí wà, kì òun lè tu ọkàn yín nínú.

  3. Mo rán Tikiku ní iṣẹ́ lọ sí Efesu.