Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Treasure: Parable of

1 ẹsẹ · 6 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Parable of

  1. “Ìjọba ọ̀run sì dàbí ìṣúra kan tí a fi pamọ́ sínú oko. Nígbà tí ọkùnrin kan rí i ó tún fi í pamọ́. Nítorí ayọ̀ rẹ̀, ó ta gbogbo ohun ìní rẹ̀, ó ra oko náà.