Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tongue: Loquacious 2 ẹsẹ · 6 abala Wá "Tongue" Gbogbo 56 Gift of 24 Restrained by wisdom 16 Confusion of 9 Language 4 Loquacious 2 Hasty 1 Àwọn ẹsẹ nípa Loquacious Òwe 10:8Ẹni tí ó gbọ́n nínú ọkàn rẹ̀ máa ń gba àṣẹ, ṣùgbọ́n ètè wérewère yóò parun.Òwe 10:19Nínú ọ̀rọ̀ púpọ̀ a kò le fẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ kù ṣùgbọ́n ẹni tí ó pa ẹnu rẹ̀ mọ́ jẹ́ ọlọ́gbọ́n.