Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of Ministers: Ministers of the sanctuary

1 ẹsẹ · 38 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Ministers of the sanctuary

  1. Yóò jẹ́ ibi mímọ́ lára ilẹ̀ náà fún àwọn àlùfáà, tí ó ń ṣiṣẹ́ ìránṣẹ́ ní ibi mímọ́ àti àwọn tí ó súnmọ́ àlùfáà ní iwájú Olúwa. Ibẹ̀ yóò jẹ ibi tí yóò wà fún ilé gbígbé wọn, bákan náà ni yóò jẹ́ ibi mímọ́ fún ilé Olúwa.