Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Scape Goat: Part of the sin offering on the day of atonement

2 ẹsẹ · 7 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Part of the sin offering on the day of atonement

  1. Òun yóò sì mú ọmọ ewúrẹ́ méjì láti ọ̀dọ̀ gbogbo àgbájọpọ̀ àwọn ọmọ Israẹli láti fi ṣe ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ wọ́n, àti àgbò kan fún ẹbọ sísun.

  2. Lẹ́yìn náà yóò sì mú ewúrẹ́ méjì náà wá sí iwájú Olúwa ní ibi ìlẹ̀kùn àgọ́ ìpàdé.