Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Sadducees: Were refused baptism by John

1 ẹsẹ · 9 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Were refused baptism by John

  1. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó rí ọ̀pọ̀ àwọn Farisi àti Sadusi tí wọ́n ń wá ṣe ìtẹ̀bọmi, ó wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin ọmọ paramọ́lẹ̀! Ta ni ó kìlọ̀ fún yín pé kí ẹ́ sá kúrò nínú ìbínú tí ń bọ̀?