Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Sadducees: Denied the resurrection and a future stated
Àwọn ẹsẹ nípa Denied the resurrection and a future stated
Ṣùgbọ́n ní ọjọ́ kan náà, àwọn Sadusi tí wọ́n sọ pé kò si àjíǹde lẹ́yìn ikú tọ Jesu wá láti bi í ní ìbéèrè,
Àwọn Sadusi kan sì tọ̀ ọ́ wá, àwọn tí wọ́n ń wí pé àjíǹde òkú kò sí wọ́n sì bi í,