Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Power of the Holy Spirit: Promised by Christ
Àwọn ẹsẹ nípa Promised by Christ
Ṣùgbọ́n ẹ̀yin yóò gba agbára, nígbà tí Ẹ̀mí Mímọ́ bá bà lé e yín; ẹ̀yin yóò sì máa ṣe ẹlẹ́rìí mi ni Jerusalẹmu, àti ní gbogbo Judea, àti ní Samaria, àti títí dé òpin ilẹ̀ ayé.”