Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The, is God Holy Spirit: As convincing of sin, of righteousness, and of judgment

4 ẹsẹ · 26 abala

Àwọn ẹsẹ nípa As convincing of sin, of righteousness, and of judgment

  1. Nígbà tí òun bá sì dé, yóò fi òye yé aráyé ní ti ẹ̀ṣẹ̀, àti ní ti òdodo, àti ní ti ìdájọ́,

  2. ní ti ẹ̀ṣẹ̀, nítorí tí wọn kò gbà mí gbọ́;

  3. ní ti òdodo, nítorí tí èmi ń lọ sọ́dọ̀ Baba, ẹ̀yin kò sì mọ̀ mí.

  4. Ní ti ìdájọ́, nítorí tí a ti ṣe ìdájọ́ ọmọ-aládé ayé yìí.