Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Euphrates

7 ẹsẹ · 14 abala

Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì

  1. Nígbà náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá nígbà kejì,

  2. “Mú àmùrè tí o rà, kí o sì fiwé ẹ̀gbẹ́ rẹ, kí o sì lọ sí Perati, kí o lọ pa á mọ́ sí pàlàpálá òkúta.”

  3. Nígbà náà ni mo lọ pa á mọ́ ní Perati gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti wí fún mi.

  4. Lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, Olúwa sọ fún mi, “Lọ sí Perati kí o lọ mú àmùrè tí mo ní kí o pamọ́ síbẹ̀.”

  5. Nígbà náà ni mo lọ sí Perati mo lọ wá àmùrè mi níbi tí mo pa á mọ́ sí, ṣùgbọ́n nísinsin yìí àmùrè náà ti bàjẹ́, kò sì wúlò fún ohunkóhun mọ́.

  6. Nígbà náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá pé:

  7. “Èyí ni ohun tí Olúwa sọ: ‘Bákan náà ni èmi yóò run ìgbéraga Juda àti ìgbéraga ńlá ti Jerusalẹmu.