Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Diet of the Jews: Of the rich, luxurious

3 ẹsẹ · 33 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Of the rich, luxurious

  1. Nígbà tí ìwọ bá jókòó láti bá ìjòyè jẹun, kíyèsi ohun tí ó wà níwájú rẹ gidigidi.

  2. Ìwọ a sì fi ọ̀bẹ lé ara rẹ ní ọ̀fun, bí ìwọ bá jẹ́ òkúndùn ènìyàn.

  3. Má ṣe fẹ́ oúnjẹ dídùn rẹ̀: nítorí pé oúnjẹ ẹ̀tàn ni.