Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Compassion and Sympathy of Christ: Weary and heavy-laden

3 ẹsẹ · 9 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Weary and heavy-laden

  1. “Ẹ wá sọ́dọ̀ mi gbogbo ẹ̀yin tí ń ṣiṣẹ́ tí a sì di ẹrù wíwúwo lé lórí, èmi yóò sì fún yín ní ìsinmi.

  2. Ẹ gbé àjàgà mi wọ̀. Ẹ kọ́ ẹ̀kọ́ lọ́dọ̀ mi nítorí onínútútù àti onírẹ̀lẹ̀ ọkàn ni èmi, ẹ̀yin yóò sì ri ìsinmi fún ọkàn yín.

  3. Nítorí àjàgà mi rọrùn ẹrù mi sì fúyẹ́.”