Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The, Are Compared To Wicked: Moth-eaten garments

2 ẹsẹ · 55 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Moth-eaten garments

  1. Olúwa Olódùmarè ni ó ń ràn mí lọ́wọ́. Ta ni ẹni náà tí yóò dá mi lẹ́bi? Gbogbo wọn yóò gbó bí aṣọ; kòkòrò ni yóò sì jẹ wọn run.

  2. Nítorí kòkòrò yóò mú wọn lá bí aṣọ, ìdin yóò sì mú wọn jẹ bí ẹ̀gbọ̀n òwú. Ṣùgbọ́n òdodo mi yóò wà títí ayérayé, àti ìgbàlà mi láti ìrandíran.”