Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tekoah: People of, work on the new wall of Jerusalem

2 ẹsẹ · 7 abala

Àwọn ẹsẹ nípa People of, work on the new wall of Jerusalem

  1. Èyí tí ó tún wà ní ẹ̀gbẹ́ wọn ni àwọn ọkùnrin Tekoa tún mọ, ṣùgbọ́n àwọn ọlọ́lá kò ṣe àtìlẹ́yìn fún iṣẹ́ náà lábẹ́ àwọn olórí wọn.

  2. Lẹ́yìn wọn ni àwọn ènìyàn Tekoa tún apá mìíràn ṣe, láti ilé ìṣọ́ ńlá tí ó yọ sóde títí dé ògiri Ofeli.