Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tarsus: Paul brought from, by Barnabas
Àwọn ẹsẹ nípa Paul brought from, by Barnabas
Barnaba sì jáde lọ sí Tarsu láti wá Saulu,
nígbà tí ó sì rí i, ó mú un wá sí Antioku. Fún ọdún kan gbáko ni wọ́n fi ń bá ìjọ péjọpọ̀, tí wọ́n sì kọ́ ènìyàn púpọ̀. Ní Antioku ni a sì kọ́kọ́ ti pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ni “Kristiani.”