Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sweat: General references

1 ẹsẹ · 3 abala

Àwọn ẹsẹ nípa General references

  1. Nínú òógùn ojú rẹ ni ìwọ yóò máa jẹun títí tí ìwọ yóò fi padà sí ilẹ̀, nítorí inú ilẹ̀ ni a ti mú ọ jáde wá; erùpẹ̀ ilẹ̀ sá à ni ìwọ, ìwọ yóò sì padà di erùpẹ̀.”