Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Stephen: Gentle and forgiving spirit of

2 ẹsẹ · 6 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Gentle and forgiving spirit of

  1. Bí wọ́n ti ń sọ Stefanu ní òkúta, ó sì ké pe Olúwa wí pé, “Jesu Olúwa, gba ẹ̀mí mi.”

  2. Nígbà náà ni ó wólẹ̀ lórí eékún rẹ̀, ó kígbe sókè pé, “Olúwa, má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ yìí sí wọn ní ọrùn.” Nígbà ti ó sì wí èyí tán, ó sùn lọ.