Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Solomon's Porch: A part of the outer court of the temple.

3 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A part of the outer court of the temple.

  1. Jesu sì ń rìn ní tẹmpili, ní ìloro Solomoni.

  2. Bí arọ ti a mú láradá sì ti di Peteru àti Johanu mú, gbogbo ènìyàn jùmọ̀ súre tọ̀ wọ́n lọ ni ìloro ti a ń pè ní ti Solomoni, pẹ̀lú ìyàlẹ́nu ńlá.

  3. A sì ti ọwọ́ àwọn aposteli ṣe iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu púpọ̀ láàrín àwọn ènìyàn. Gbogbo wọn sì fi ọkàn kan wà ní ìloro Solomoni.