Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shadrach: Called also Hananiah, a Hebrew captive in Babylon.
Àwọn ẹsẹ nípa Called also Hananiah, a Hebrew captive in Babylon.
Nígbà náà ni Daniẹli padà lọ sí ilé e rẹ̀, ó sì sọ fún àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ rẹ̀ Hananiah, Miṣaeli àti Asariah.
Daniẹli béèrè lọ́wọ́ ọba, ó sì yan Ṣadraki, Meṣaki, àti Abednego gẹ́gẹ́ bí alábojútó ìgbèríko Babeli ṣùgbọ́n Daniẹli fúnra rẹ̀ wà ní ààfin ọba.