Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Serah: Called also Sarah, daughter of Asher.

3 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Called also Sarah, daughter of Asher.

  1. Àwọn ọmọkùnrin Aṣeri: Imina, Iṣifa, Iṣfi àti Beriah. Arábìnrin wọn ni Sera. Àwọn ọmọkùnrin Beriah: Heberi àti Malkieli.

  2. (Orúkọ ọmọ Aṣeri obìnrin nì jẹ́ Sera.)

  3. Àwọn ọmọ Aṣeri: Imina, Iṣifa, Iṣfi àti Beriah. Arábìnrin wọn sì jẹ́ Sera.