Skip to content

Serah

3 ẹsẹ · 5 ọmọ ẹbí

A tún mọ̀ ọ́n sí: Sarah

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Serah

  1. Àwọn ọmọkùnrin Aṣeri: Imina, Iṣifa, Iṣfi àti Beriah. Arábìnrin wọn ni Sera. Àwọn ọmọkùnrin Beriah: Heberi àti Malkieli.

  2. (Orúkọ ọmọ Aṣeri obìnrin nì jẹ́ Sera.)

  3. Àwọn ọmọ Aṣeri: Imina, Iṣifa, Iṣfi àti Beriah. Arábìnrin wọn sì jẹ́ Sera.