Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Segub: 2. Grandson of Judah

4 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 2. Grandson of Judah

  1. Tamari, aya ọmọbìnrin Juda, ó sì bí Peresi àti Sera sì ní ọmọ márùn-ún ní àpapọ̀.

  2. Àwọn ọmọ Peresi: Hesroni àti Hamulu.

  3. Nígbà tí ó yá, Hesroni sì dùbúlẹ̀ pẹ̀lú ọmọbìnrin Makiri baba Gileadi (ó sì ti fẹ́ ní aya láti ìgbà tí ó ti wà ní ẹni ọgọ́ta ọdún) ó sì bí Segubu.

  4. Segubu sì jẹ́ baba Jairi, ẹni tí ó jẹ́ olùdarí ìlú mẹ́tàlélógún ní ilẹ̀ Gileadi.