Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sea: Dead to be given up by the sea at the resurrection
Àwọn ẹsẹ nípa Dead to be given up by the sea at the resurrection
Òkun sì jọ̀wọ́ àwọn òkú tí ń bẹ nínú rẹ̀ lọ́wọ́; àti òkú àti ipò òkú sì jọ̀wọ́ òkú tí ó wà nínú wọn pẹ̀lú: a sì ṣe ìdájọ́ wọn, olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ wọn.