Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salome: Asks Jesus to promote her sons

2 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Asks Jesus to promote her sons

  1. Nígbà náà ni ìyá àwọn ọmọ Sebede bá àwọn ọmọ rẹ̀ wá sọ́dọ̀ Jesu, ó wólẹ̀ lórí eékún rẹ̀, o béèrè fún ojúrere rẹ̀.

  2. Jesu béèrè pé, “Kí ni ìwọ ń fẹ́?” Ó sì dáhùn pé, “Jẹ́ kí àwọn ọmọ mi méjèèjì jókòó ní apá ọ̀tún àti apá òsì lórí ìtẹ́ ìjọba rẹ?”