Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rocks: Man's industry in cutting through
Àwọn ẹsẹ nípa Man's industry in cutting through
Ó fi ọwọ́ rẹ̀ lé akọ òkúta, ó yí òkè ńlá po láti ìdí rẹ̀ wá.
Ó sì la ipa odò ṣíṣàn nínú àpáta, ojú inú rẹ̀ sì rí ohun iyebíye gbogbo.