Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Resignation: Submission to the sovereignty of God in his purposes

2 ẹsẹ · 30 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Submission to the sovereignty of God in his purposes

  1. Bẹ́ẹ̀ kọ́, ìwọ ènìyàn, tà ni ìwọ tí ń dá Ọlọ́run lóhùn? “Ohun tí a mọ, a ha máa wí fún ẹni tí ó mọ ọ́n pé, ‘Èéṣe tí ìwọ fi mọ mi báyìí?’ ”

  2. Amọ̀kòkò kò ha ni agbára lórí amọ̀, nínú ìṣù kan náà láti ṣe apá kan nínú ohun èlò sí ọlá, àti apá kan nínú ohun èlò sí àìlọ́lá?