Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rechab: 3. Father of Malchiah
Àwọn ẹsẹ nípa 3. Father of Malchiah
Ẹnu ibodè Ààtàn ni Malkiah ọmọ Rekabu, alákòóso agbègbè Beti-Hakeremu tún mọ. Ó tún un mọ, ó sì gbé àwọn ìlẹ̀kùn rẹ̀, àwọn ìdábùú ìlẹ̀kùn àti àwọn ìdè rẹ̀ sí ààyè wọn.