Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Raguel: Moses' father-in-law

1 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Moses' father-in-law

  1. Mose sì sọ fún Hobabu ọmọ Reueli ará Midiani tí í ṣe àna rẹ̀ pé, “A ń gbéra láti lọ sí ibi tí Olúwa sọ pé, ‘Èmi ó fi fún un yín.’ Bá wa lọ, àwa ó ṣe ọ́ dáradára nítorí pé Olúwa ti ṣèlérí ohun rere fún Israẹli.”