Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Rabbi: Used in addressing John

1 ẹsẹ · 6 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Used in addressing John

  1. Wọ́n sì tọ Johanu wá, wọ́n sì wí fún un pé, “Rabbi, ẹni tí ó ti wà pẹ̀lú rẹ lókè odò Jordani, tí ìwọ ti jẹ́rìí rẹ̀, wò ó, òun tẹ àwọn ènìyàn bọ omi, gbogbo ènìyàn sì ń tọ̀ ọ́ wá.”