Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Queen: Sits on the throne with the king

1 ẹsẹ · 9 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Sits on the throne with the king

  1. Nígbà náà ni ọba, pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ tí ó jókòó lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, bi mí pé, “Báwo ni ìrìnàjò náà yóò ṣe pẹ́ ọ tó, nígbà wo sì ni ìwọ yóò padà?” Ó dùn mọ́ ọba láti rán mi lọ, bẹ́ẹ̀ ni mo dá àkókò kan.