Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pomegranate: Brought by the spies to show the fruitfulness of the land of Canaan
Àwọn ẹsẹ nípa Brought by the spies to show the fruitfulness of the land of Canaan
Nígbà tí wọ́n dé àfonífojì Eṣkolu, wọ́n gé ẹ̀ka kan tó ní ìdì èso àjàrà gireepu kan. Àwọn méjì sì fi ọ̀pá kan gbé e; wọ́n tún mú èso pomegiranate àti èso ọ̀pọ̀tọ́ pẹ̀lú.