Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Palace: Figurative, of a government
Àwọn ẹsẹ nípa Figurative, of a government
Èmi yóò rán iná sí orí Temani, tí yóò jó gbogbo ààfin Bosra run.”
Èmi yóò rán iná sí orí Moabu èyí tí yóò jó àwọn ààfin Kerioti run. Moabu yóò sì kú pẹ̀lú ariwo pẹ̀lú igbe àti pẹ̀lú ìró ìpè.
A ó ṣí ìlẹ̀kùn àwọn odò wọ̀n-ọn-nì sílẹ̀, a ó sì mú ààfin náà di wíwó palẹ̀.